About IROYIN TV

    Iroyin TV je agbekale oro ti o ti seleri ati oro ohun ti o lo lawujo wa,nile yi ati leyin odi,lori amoju too,iroyin idagba soke ilu lori ilosi waju awon ajogunba ati ohun amuse agbara gege bi ohun inii wa,lati leni aboo ti o peye ati ifokan bale lori akiyesi ohun ti o lo lagbegbe ati agbala ayie papa julo lawujo wa,nile kootu oji re,isedale wa,orirun wa,lori idaraya,ere itage ayeye iroyin eto ilu nile yoruba pelu awon agbekale asa ati ise iran yoruba.eleyi je ero amowun maworan iroyin igbalode ti o tepepe iroyin lolokan o jokan lori ohun ti o lo lawujo wa,sise afihan iroyin ti o je oju lowo,ewa ede yoruba,lede abinibi wa,ede omo oluwabi yoruba ponbeele.iroyin ayeye,eto abinibi ati agbami iroyin orisirisi...asa iran yoruba 'o' le parun. Fun ipolowo,iru ebun wo niwo ni,olorin,onise owo,onisowo,onilese nla,ijo olorun gbogbo tabi osere,kini nkan ti o yan layoo tio selowo epe wa sori/ whatsaap: 08111718824.

    Iroyin, eto, ayeye, odun abinibi ati agbami oro tolo l'orisirisi asa iran yoruba 'o' le parun. (iroyin event,festival &news series channel).